CULTURE PROMOTION WITH ANIKY EPISODE 5: AṢA OGE ṢÍṢE NÍ ILẸ YORÙBÁ

in #culture6 years ago

E ku dede asiko yi eyin eyan mi, mo si tun kiwa ku atigba lori eto yi, eto yin eto wa ti a fin gba asa ga lori steemit latun muwa fun yin loni. A ko ni anfani lati se eto yi ni bi ose die seyin nitori eniyan wa kan, ore wa, egbon wa ti o se alaisi lori steemit, Eni ti oruko re nje @Onos. Ki oluwa ko ba wa tee si afefe rere.

Ohun ti ao maa gbe yewo lori eto yi loni ni AṢA OGE ṢÍṢE NÍ ILẸ YORÙBÁ.

Oge Sise je okan ninu asa ile yoruba ti o nise pelu bi a ti se n tun ara wa se.

Lalai se afikun tabi ayokuro otito, oge sise ni ile yoruba je ohun ti awa odo ode oni ti fi owo ro seyin nitori awon asa oyinbo ti o de loni.

Ai mo anfani ati iyi ti o wa nibi oge sise ati sise ewa ni Ile Yoruba ni isori ohun ti awa odo iwoyi ko fi pataki OGE ṢÍṢE.

Ni aye ode oni ti a ba ri eni ti o ko ila, awon odo ati awon akegbe re yio maa fi se yeye nitori pe won ri ila kiko gegebi ohun aye atijo ti ko ye ki a maa ri ni ode oni mo, tabi ti aba ri eni ti o wo agbada, dansiki, buba, iro ati buba tabi eni ti o se awon irun bii ipako elede, kojusoko keyinsale, won a maa wo won bi eni ti ko ri ookan, bee awon ohun ti o n bu ewa kun asa ati ise ile yoruba ni awon nkan wonyi. Ki wa ni awon ohun ti a fi n se oge ni ile yoruba wa, ema bami kalo ninu eto yi:

  • Osun kikun
  • Laali Lile
  • Eti lilu
  • Irun didi
  • Ori fifa
  • Ila kiko

Laali Lile: Asa laali lile je ohun ti awon yoruba ko lati odo awon Hausa, nitoripe awon ni won maa le laali lati ibere pepe. A ni ewe igi ti a mo si ewe laali, a maa n kun ewe yi , ao fi kaun si, ao si fisi ibi ti a ba fe le laali naa si ni ara wa.


*Image Credit

Tiro Lile: tiro ninu tun je ohun ti o se pataki ninu isaraloge ile yoruba, yato si wipe a maa n fi tiro se oge, tiro tun dara fun oju wa, a maa ko idoti kuro ninu oju, a si maa je ki oju rina kedere. Ati okunrin, ati obinrin ni o le le tiro sugbon obinrin ni o poju ninu awon ti o maa n le tiro .

Ila Kiko: Ila kiko je ona ti awon yoruba fi n se oge ni aye atijo, awon babanla wa a maa ko ila fun omo lati bu ewa kun oju omo naa, won a si tun maa ko ila fun omo lati fi se ipin laarin omo won ati omo elomiran paapaa julo laarin eya kan si ikeji, orisirisi ila kiko ni o wa, eya orisirisi si ni o ni bi won ti se n ko ila tiwon, tofi je wipe ti awon eniyan ba ti ri ila yi loju eniyan kan, won ti mo ibi ti eni naa ti wa.


Source


Source.

Eti Lilu: Eti lilu lati fi se oge je ohun ti awon obinrin nikan gbudo maa se ti okunrin kosi gbodo kopa nipe, Awon obinrin maa n lu eti won lati fi yeri eti si, yeri eti ti a fi orisirisi iyun ati ileke se, ti yio si maa muwon rewa si.

Irun didi: Orisirisi ara ni awon obinrin yoruba maa n fi irun da, won a maa se irun ori won lati fi se oge, ni igba miran, won a maa fi ileke si lati gbe ewa won yo daradara.


Source

Irun Fifa: Nigbati awon obinrin ba n di irun won, awon okunrin naa a maa fa ori won, ona ti o ba wuwon ni won fi le fa, ti yio si maa gbe ewa tiwon naa yo gegebi okunrin. Ayafi awon ti a mo si Ilari oba, ti won maa n fi die le ninu ori won lati fi han pe ilari niwon.


Source

TRANSLATION


Greetings to my people here on steemit, here is another episode of your Culture Promotion Show by Aniky, My greetings to us all,

It been a while on this show, My show and the show for you that Promote Culture On The Steem Blockchain is back from long time leave.

Today on this show, we will be discussing BEAUTIFICATION IN YORUBALAND.

Beautification in Yoruba land is that part of the Yoruba Tribe that entails how we take carer of our body making it look good all the time. Without adding to or subtracting from the truth, Beautification in Yoruba Land is one of those things the Yoruba Youths of today don't want to listen to or practice anymore because of the modern day civilisation.

Lack of knowledge on the benefits of Yoruba Beautification is the main reason why the youths of today gives less importance to it.

In our modern world of today, if the youths come across a person with tribal marks, they make jest and tagged that person as a local and not civilised person because they see tribal marks as a style of the olden days people,

when youths also come across their friend putting on Agbada, Dansiki or Buba(For Male), iro and Buab (for female), or a lady that made some olden days hairstyle like ipako elede, kojusoko keyinsale, they tagged them as not being in town because they are now new civilised hairstyles for modern ladies.


Credit

Whereas these olden days practices are the real beauty of our Culture. Below are those things the Yorubas see as Beautification;

  • Painting some part of the body with Laali (Dried Henna Powder is what we refer to as Laali).
  • Piercing the Ear
  • Plaiting of Hair
  • Barbing the Hair and
  • Facial Tribal marks

Facial Tribal Marks: This is one of the major Beautification for both male child and female child which our fathers during the olden days believe that it beautifies their children so much. They also see it as a way to recognize their children most especially between different ethnic groups.

Piercing The Ear: This is majorly for the female child, where they are expected to put in earrings and beads to make them more beautiful than they were before.

Plaiting of Hair: This is also for the Female child, the hairdresser create different beautiful hairstyle for the females which beautify them alot and makes them looks extraordinarily attractive.

Barbing of Hair: This is for the Male child, they barb their hair and they only have one hairstyle which is cutting off all the hair they have remaining only their scalp except for the king guards whom leave little of their hair at the front to show that they are the kings guards. The Yorubas call them ILARI

See the Yoruba Session for Pictures.

FUN CORNER


WhatsApp Image 2018-09-06 at 8.20.21 PM.jpeg

WhatsApp Image 2018-09-06 at 8.20.20 PM.jpeg

WhatsApp Image 2018-09-06 at 8.20.20 PM (2).jpeg

IQ TEST


GIVE THE WORDS IN THE PICTURE BELOW CORRECTLY AND WIN A RECHARGE VOUCHER OF YOUR CHOICE.

LET'S GO>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>>
WhatsApp Image 2018-09-06 at 8.20.20 PM (1).jpeg

APPRECIATION
SPECIAL APPRECIATION
I specially appreciate everyone who took their time to join me on this show.
@eurogee, @smyle, @drigweeu,@adoore-eu, @zoneboy, @zizymena, @sweetestglo-eu, @jeaniepearl, @surpassinggoogle, and @euronation members.

STAY COOL TILL I COME NEXT WEEK,
THE SAME TIME
THE SAME BLOG.

LOVE YOU ALL »»»»»»KISSES»»»»»>MUAH!!!

IF You Love this, Don't Forget To>>>>>>>>>>>>>>>>

WhatsApp Image 2018-09-06 at 9.01.09 PM.jpeg

Picture Designed by
WhatsApp Image 2018-08-29 at 10.30.58 PM.jpeg.

JUST WHATSAPP @+234 805 420 4298.

Sort:  

Culture is lovely. Wish we all uphold our cultures

Posted using Partiko Android

Dear friend, you do not appear to be following @wafrica. Follow @wafrica to get a valuable upvote on your quality post!

Wow, another beautiful episode.
Well you know some ladies, still do the laali of a thing. And it usually beautiful.
And the tribal mark? Dont even say that again (they should punish those that tear babies skin like that.) Hahahaha
And most of those hair are still in vouge, just that it been rebranded and made civil.
Great work babe👏👏😘

Send my recharge card to 08078865177 😂😂

My answers are
He
To
Oh
Hole
Thole

I will insert the words and if they are correct .........You will see the screenshot

Coin Marketplace

STEEM 0.15
TRX 0.15
JST 0.028
BTC 54179.48
ETH 2261.18
USDT 1.00
SBD 2.31